Ìbọn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Ìbọn jẹ́ ohun èlò ogun tí ẹnìkan lè mú tàbí gbé dání lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo. Wọ́n ṣe ìbọn fún yínyìn pẹ̀lú ọta tàbí àhàyá. [1] ó le ṣeé lò dára dára, wọ́n ma ń gbé ìbọn dání pẹ̀lú ọwọ́ méjèjì, tí wọn yóò sì fi ìdí rẹ̀ ti èjìká kí ó má ba jábọ́ lásìkò tí wọ́n bá ń yìn ín lọ́wọ́. Irúfẹ́ ìbọn wọ̀nyí ni a mọ̀ sí ìbọn gígùn. Àwọn èyí tí ó jẹ́ ìbọn pélébé tàbí ìbọn ìléwọ́ kìí nílò láti fi ọwọ́ méjèjì mu kí ó tó ṣiṣẹ́. [2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Mizokami, Kyle (2018-03-08). "Different Types of Guns and Gun Safety Tips - How a Gun Works". Popular Mechanics. Retrieved 2020-04-24. 
  2. "Rifle - weapon". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2020-04-24.