Jump to content

Ìdádúró Lílùọkàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìdádúró Lílùọkàn
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta
ICD/CIM-10I46. I46.
ICD/CIM-9427.5 427.5

Ìdádúró Lílùọkàn tabi idaduro ayikakiri (cardiac arrest tabi circulatory arrest) je idaduro lojiji bi èjè se n yikakiri ninu ara nitori ikuna okan lati lu bo se ye.

Idaduro okan yato si ikolu okan (heart attack)