Ìkún omi Accra ọdún 2016
Ìrísí
Ìkún omi Accra ọdún 2016 ṣẹlẹ̀ nítorí òjò líle tí ó rọ̀ ní Accra, olú ìpínlẹ̀ Ghana ní oṣù kẹfà ọdún 2016. Ìkún omi náà ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹfà ọdún 2016.[1] Ìgbà tí ó ṣe ma di ọjọ́ keedogun oṣù kẹfà ọdún 2016, ìkún omi náà ti pa tó ènìyàn mẹ́wàá.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Lowe, Jonathan (June 14, 2016). "Ghana: Watch video of Accra floods that turned streets into rivers after just 6 hours of rain". International Business Times. http://www.ibtimes.co.uk/ghana-watch-video-accra-floods-that-turned-streets-into-rivers-after-just-6-hours-rain-1565398. Retrieved June 15, 2016.
- ↑ "At least 10 dead in Ghana floods". The Straits Times. June 15, 2016. http://www.straitstimes.com/world/at-least-10-dead-in-ghana-floods. Retrieved June 15, 2016.