Ìmò Ìṣirò
Oju Ewe Imo Isiro
Ìmọ̀ Ìsirò jẹ́ èyí t'on jẹ mo nipa ọ̀pọ̀iye (quantity), nipa òpó (structure), nipa iyipada (change) ati nipa ààyè (space). Idagbasoke imo Isiro wa nipa lilo àfòyemọ̀ọ́ (abstraction) ati Ọgbọ́n ìrọ̀nú, pelu onka, isesiro, wíwọ̀n ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri (shapes) ati bi won se n gbera (motion). Eyi ni awon Onimo Isiro n gbeyewo, ero won ni lati wa aba tuntun, ki won o si fi ootọ́ re mulẹ̀ pelu itumo yekeyeke.
A n lo Imo Isiro ka kiri agbaye ni opolopo ona ninu Imo Sayensi, Imo Ise Ero, Imo Iwosan, ati Imo Oro Okowo. Bi a se n lo imo Isiro bo si apa eyi ti a n pe ni Imo Isiro Oníwúlò (Applied Mathematics). Apa keji Imo Isiro ni a mo si Imo Isiro Ogidi. Eyi je mo eko imo isiro to ko ti ni ilo kankan bo tileje pe o se se ki a wa ilo fun ni eyinwa ola.
Awon Orisirisi Nomba ti o wa
- Nọ́mbà Àkọ́kọ́
- Nọ́mbà Pípé
- Nọ́mbà Sísẹ́kù
- Nọ́mbà Tíkòsí
- Nọ́mbà Apáòsì
- Nọ́mbà Apáọ̀tún
- Nọ́mbà Àdábá
- Nọ́mbà Odidi
Awon Eka Imo Isiro
Eko Isiro | Ipilese Imo Isiro | Ero Nomba | Imo Isiro Onijinle |
---|---|---|---|
Agbeyewo Ninu Imo Isiro | Aljebra | Iwon Itobile ati Imo Eya Ile | Imo Isiro Oniwulo |