Itoro Umoh Coleman
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ìtọrọ umoh coleman)
Guard | ||||||||||||||
Personal information | ||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Born | 21 Oṣù Kejì 1977 Washington, D.C. | |||||||||||||
Nationality | Amerika | |||||||||||||
Listed height | 5 ft 7 in (1.70 m) | |||||||||||||
Listed weight | 140 lb (64 kg) | |||||||||||||
Career information | ||||||||||||||
High school | Hephzibah (Hephzibah, Georgia) | |||||||||||||
College | Clemson (1995–1999) | |||||||||||||
NBA draft | 1999 / Undrafted | |||||||||||||
Pro playing career | 2003–2003 | |||||||||||||
Career history | ||||||||||||||
2003 | Houston Comets | |||||||||||||
Medals
|
Itoro Umoh-Coleman (ọjọ́ ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejì ọdún 1977) jẹ́ òní ère ìdárayá ọmọ orílẹ̀-èdè Amerika àti agbábọ́ọ̀lù àfọwọ́gbá tẹ́lẹ̀rí fún ẹgbẹ́ WNBA. Ó gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Clemson Tigers ní ìgbà tí ó wà ní ilé-ìwé, ó sì jé adarí ẹgbẹ́ náà.[1][2] Ní ọdún 2002, Atlantic Coast Conference yan Itoro fún '50-year all star women's basketball team,' àti fún '25th Anniversary Tournament' team[3]
Ìgbé ayé ìbéèrè pẹpẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí ní Washington, D.C., Umoh-Coleman dàgbà ní Hephzibah, Georgia. Ó lọ sí Hephzibah High School, ó sì gbá bọ́ọ̀lù àfọwọ́gbá fún ẹgbẹ́ the Lady Rebels lábẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá Wendell Lofton.[4] Ó ka ẹ̀kọ́ gboyè ní ọdún 1995. [5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ WNBA Player Bio Archived 2011-05-25 at the Wayback Machine.
- ↑ "Clemson fires Itoro Coleman". ESPN. March 8, 2013. Retrieved 8 Mar 2013.
- ↑ "Overtime", Augusta Chronicle, 5 May 2005. Retrieved 03-03-2009.
- ↑ Tim Morse, "Discipline key to Hephzibah's success", Augusta Chronicle, January 18, 1999. Retrieved 03-03-2009.
- ↑ Tim Morse, "Discipline key to Hephzibah's success", Augusta Chronicle, January 18, 1999. Retrieved 03-03-2009.