Jump to content

Ìyá ìlù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Iyaalu Drum 2

Ìyá Ìlù Ìyá ìlù jẹ́ ìlù ilẹ̀ adúláwọ̀ tí wọ́n gbẹ́ gẹgẹ́ bí dígí tí wọ́n fi ń ka wákàtí láyé àtijọ́ , pàáv pàábjùlọ ní lẹ̀ Yorùbá. Wọ́n ma ń fi Ìyá ìlù sọ̀rọ̀ gẹ́gẹ́ bí eni wípé ènìyàn ni ó ń sọrọ̀ nígbà tí wọ́n bá lo ìwọ́hùn ènìyàn láti fi lu ìlù náà.

wọ́n gbẹ́ gẹgẹ́ bí dígí tí wọ́n fi ń ka wákàtí láyé àtijọ́, nígbà tí wọ́n fi awọ ewúrẹ́ bòó níwájú àti lẹ́yìn, tí wọ́n sì fi àwọn awọ tẹ́ẹ́rẹ́ ṣe okùn tí ó so àwọn awọ méjèèjì pọ̀ mọ́ ara wọn láàrín. Àwọn awọ tẹ́rẹ́ wọ̀nyí ni omílù yóò fọwọ́ kọ́ tí yóò sì ma fi apá fun mọ́ra áti lè fun ní irúfẹ́ ìwọ́hùn tí ó bá fẹ. Ẹni tí ó bàv jẹ́ Ààyàn tó bác yanjú yóò lè lo ìlù náà láti fibsọ ohun kóhun tó bá fẹ́. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwon ìyá ìlù ló ma ń sọ̀rọ̀ bí ènìyàn. Àmọ́, ó dá lóri bí onílù bá ṣe lùú. Lára àwọn ìlù tí wòn fara jọ ìyá ìlù tí wọ́n fi gẹgẹ́ bí dígí tí wọ́n fi mń ka wákàtí láyé àtijọ́ náà wà ní agbàègbè ilẹ̀ Éṣíà, ṣùgbọ́n wọn kìí lòó láti fi sọ̀rọ̀ bí ti ilẹ̀ Adúláwọ̀. Àmọ́ ṣá wọ́n ma ń lo ìlù idakka láti fi gbe orin lẹ́sẹ̀.

Àwọn ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Ẹ̀kúrẹ́rẹ́