Jump to content

Ìyípadà Àwọn Ìlànà Òjò Láti Ọdún 1970 ní Afónifójì Rift, Kenya

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwọn ọmọdé tó ń ṣeré nígbà tí òjò ṣetán láti máa rọ̀ ní Kenya

Àwọn ìlànà òjò ní àkókò tí àwọn ohun ọ̀gbìn fẹ́ máa hù ti oṣù kẹrin àti oṣù karùn-ún ti ń sún mọ́lé tí ń yípadà ní àwọn ọdún díẹ̀ sẹ́yìn ní agbègbè Rift Valley, Kenya.  Láti àwọn ọdún 1970, níṣe ni òjò yìí ń pọ̀ níye àmọ́ ìdínkù wà nínú àwọn ọjọ́ tó fi ń rọ̀. Èyí ti yọrísí ìlọsókè tí kíkankíkan òjò.

Àwọn ìlànà òjò lákokọ̀ àkókò ìdàgbàsókè

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]