Òjògbón Abdulrasheed Na'Allah
Ìrísí
Ọ̀jògbón Abdulrasheed Na'allah tí a bi ní ìlú Ilorin, ní ìpínlè kwara, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[1], a bi ní ojó kokànlélógún, oṣù kejìlá(December 21), ọdún 1962 [1]. Òjògbón Abdulrasheed ni olori ilé-ẹ̀kọ́ yunifásitì ìpínlè Kwara láàárín ọdún 2009 sí ọdún 2019. ósì di olori ilé-ẹkọ́ Yunifásitì ti ìlú Àbújá ní odun 2019 [2] ipò tí ó wà titi di asiko ti a n kọ àyọkà yí. Ojogbon Abdulrasheed keko gboyè nínú ìmò Art(Bachelor of Art) ní yunifásitì Ìlorin ní odun 1988, o si tún kẹkọ gboyè nínú ìmò literature Gẹẹsi ni le-ẹkọ yunifásitì kanáà ní odun 1992 [3]., Òjògbón Abdulrasheed ti kọ ìwé tí ó pọ̀. Lára rẹ ni
- Seriya,
- Omolekewu
- Ilorin fa
- Yoruba Oral Traditions
- Africa Discourse [4]
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Prabook". prabook.com. Retrieved 2022-03-02.
- ↑ Olufemi, Alfred (2021-03-14). "EXCLUSIVE: UNIABUJA VC left KWASU with 'huge' retirement package despite school's indebtedness". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-03-02.
- ↑ "Prof Na’allah takes over as UniAbuja VC". Daily Trust. 2019-07-02. Retrieved 2022-03-02.
- ↑ Omolaoye, Sodiq (2021-07-04). "With Seriya, Omokewu, Na’Allah deepens Islamic study". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2022-03-02. Retrieved 2022-03-02.