Jump to content

Òmìnira

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán ètò ìṣèjọba àwọn Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan.

Ominira jẹ́ ìṣèjọba ara ẹni ni ilẹ̀-abínibí, orílẹ̀-èdè, tàbí gbígba ilẹ̀-ìjọba kan kúrò lọ́wọ́ àwọn olùjẹ gàba le lórí.