Jump to content

Ẹ̀gbà Ọrùn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Diamond and garnet necklace

Ẹ̀gbà Ọrùn jẹ́ ohun tí àwọn ènìyàn, ọkùnrin àti obìnrin n lo lati fi se eṣọ́ ara. [1] Àwọn ènìyàn sábà ma ń lòó níbi àwọn ayẹyẹ bíb: ayẹyẹ, ẹ̀sìn, or ìsìnkú, ìkómọ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ó tún wà fún ṣíse àdáyanrí tàbí ìyàtọ̀ láàrín olówó àti tálíkà láàrín àwùjọ. Ọ̀pọ̀ nínú àwọn ẹ̀gbà ọrùn wọ̀nyí ni wọ́n fi ohun èlò oníyebíye ṣe. Papòọ̀ nínú àwọn ẹ̀gbà ọrùn yí ni wọ́n ma ń ṣe pẹ̀lú ìlẹ̀kẹ̀ yálà iyùn sẹ̀gi, tàbí àko àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn ẹ̀gbà ọrùn míràn ni wọ́n di góólù, ìdẹ, bàbà àti àwọn òkúta oníyebíye mìíràn ṣe. [2] Ninu awon ohun eso ara, egba orun da yato fun awon ti won n loo fun isaraloge.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Davenport, Cyril (1902). "Journal of the Society for Arts, Vol. 50, no. 2595". The Journal of the Society of Arts 50 (2595): 769–780. doi:10.2307/41335652. JSTOR 41335652. 
  2. "A Glossary of 16 Necklace Styles". The Spruce Crafts. Retrieved 2019-12-17. 
  3. Smith, Jennifer (2023-07-22). "Why Necklaces Are a Crucial Element in Your Fashion Arsenal". The Fox Magazine. Retrieved 2024-12-11.