Ẹsẹ̀
Appearance
Ẹsẹ̀ jẹ́ ẹ̀yà ara tó ń mára dúró, tó sì wà fún gbígbé ara láti ibìkan lọ sí ibòmííràn. Lásìkò gbígbé ara láti ibìkan lọ ibòmìíràn, ẹsè máa ń nà.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Leg - Definition, Bones, Muscles, & Facts". Encyclopedia Britannica. 1999-05-27. Retrieved 2023-02-05.