Ọ̀rọ̀:Benin
Mo L'ero wipe bi a se n fi Yoruba da K'ko sile ni Orile-Ede Bini, yato si bi a se N fi Yoruba da Kiko sile Ni Orile-ede Naijiria, Ni tori wipe, Ede Naijiria je Orile-Ede Ti o N so Ede Ingilishi, Ama Orile Ede Benin N so Faranse. Nitori idi eyi, bu ede naa se n da kiko sile ni orile-ede mejeeji, yato sira. Fun Apere: Orile-Ede Naijiria Orile-Ede Bini. Name:Oruko Nom:Orouko Flag: Asia Drapeau:Achia
Nitori Idi eyi, ojo-ewe Wikipedia fun orile-ede Bini, ye ki o fi iyato yii si Iranti, ni kiko oju-ewe fun orile-ede naa, nitori Omo-Yoruba lati Bini, ti o ba ri oju-ewe yii ,O ni le kaa, daa-daa. Ese Pupo.
Start a discussion about Benin
Talk pages are where people discuss how to make content on Wikipedia the best that it can be. You can use this page to start a discussion with others about how to improve Benin.