Ọ̀rọ̀:Dúró Ládipọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Mi ò rò wípé ó yẹ kí oníṣé T Cells ó fi léde láti yọ ojú ewé Dúró Ládípọ̀ kúrò nínú ìwé ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ nítorí wípé kò gbé ẹnìkẹ́ni lárugẹ tàbí polówó ọjà tàbí oníbàrà kan kan, ojú ewé yìí wà ní ìbámu pẹ̀lú ẹ̀dà en.wikipedia. Mi ò bá rọ̀ yín kí ẹ tún ìpinnu yín yẹ̀wò lẹ́ẹ̀kan si. Ẹ ṣé Agbalagba (ọ̀rọ̀) 13:10, 22 Oṣù Kàrún 2018 (UTC)