Ọ̀rọ̀:Oro

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Oro wa ninu ajodu nla ti awon Yoruba man n se ni odoodun. Odun Oro je okan pataki odun ninu gbogbo odun ti awon oloro lara eya Yoruba n se.

Oro si je osa kekere kan ti a mo si olorun ogun. Ara igi agbon lati gbe Oro jade. Osa nla gidi gan ni Oro je, won a si ma boo ni odoodun.

 

Oro je osa kan to sepe omo okunrin nikan lo le foju ri to si le boo paapaa julo lodo awon ti ajodun yii ba tan mo. A ki wo ni Oro fun eni ti ko ba n se omo oloro pelu fun obinrin lapaapo. Gbogbo obinrin pelu eni ti ko ba tan mo oloro ni lati wa ni asemo lasiko ti odun Oro ba waye. Ewe, obinrin o gbodo fi oju kan osa yi ti a n pe ni Oro. Bi obinrin ba foju kan Oro, Oro a gbe.

 

Orisirisi ona ara, asa ati ise ni awon oloro ma n gba se odun yii. Osi yato lati ipinle si ipinle ati ilu si ilu. Ni awon akoko miran, Oro a ma jade, tabi ki won gbe oro fun eni pataki bii oba to ba je olori awon to n boo orisa yii (Oro).

 

Bi Oro se bere

Ni aye atijo, osa merin kan wa ton n gbe ni Erekusu. Awon osa won yi so di mimo pe: Ta'aroa, Iyemoja (god of the sea), Tane, Oluigbo (god of the forest), Tu, (Jagunmolu atijo) ati Ro'o, (olorun nkan ogbin pelu bi oju ojo tinri).