Ọ̀rọ̀ ìṣe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọ̀rọ̀ ìṣe ni ọ̀rọ̀ tí ó ń fi ohun tí a ń ṣe lọ́wọ́ tí a ti ṣe kọjá tàbí ohun tí a óò ma ṣe lọ́jọ́ iwájú hàn nínú gbólóhùn.[1] Èyí ni kókó inú gbólóhùn èdè Yorùbá, òhun ni ó wà láàrin Olúwa àti àbọ̀, ó lè ṣíwájú ólùwa ó sì lè síwájú àbọ̀, òpómúléró inú gbólóhùn ni ọ̀rọ̀ ìṣe jẹ́.[2]

Àwọn Ìtọ́kas sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Shrives, Craig. "What are verbs?". Free English grammar tests. Retrieved 2020-03-22. 
  2. "#1 Grammar and Spell checker". Ginger Software. 2020-03-22. Retrieved 2020-03-22.