Jump to content

Ọjà Pàṣípàrọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
An 1874 newspaper illustration from Harper's Weekly, showing a man engaging in barter: offering various farm produce in exchange for his yearly newspaper subscription.

Ọjà Pàṣípàrọ̀ jẹ́ ètò ṣíṣe pàṣípàrọ̀ ohun-ìní tàbí iṣẹ́ láàárín ènìyàn méjì láyé àtijó nígbà tí wọn kò ì tíì ṣẹ̀dá owó fún káràkátà ṣíṣe. Bí àpẹẹrẹ, ẹni tí ó bá ní ìṣù ṣùgbọ́n tí ó nílò gaàrí yóò wá ẹlòmíràn tí ó ní gaàrí tí ó sìn nílò iṣu láti ṣe pàṣípàrọ̀ pẹ̀lú rẹ̀. Ọjà Pàṣípàrọ̀ jẹ́ ọ̀nà tí wọ́n ń gbà ṣe káràkátà láyé àtijó láìlo owó. [1] [2] [3] [4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Trade by Barter". Passnownow. 2016-08-05. Retrieved 2019-12-31. 
  2. "Barter Exchange: Meaning and Problems of Barter Exchange". Economics Discussion. 2014-02-15. Retrieved 2019-12-31. 
  3. "What does barter mean? definition and meaning". BusinessDictionary.com. 2019-12-26. Archived from the original on 2019-12-19. Retrieved 2019-12-31. 
  4. Kenton, Will (2003-11-19). "Barter (or Bartering) Definition". Investopedia. Retrieved 2019-12-31.