Jump to content

Ọjọ ọsẹ òyìnbó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọjọ́ ọ̀sẹ̀ òyìnbó ni àwọn orúkọ tí à ń pe ọjọ́ tí a ní nínú ọ̀sẹ̀, èyí tí àwọn òyìnbó mú wá.[1] Ki ẹ̀sìn àtọ̀hùn-rìn-wà tó tàn kárí ayé, òrìṣà ni àwọn ènìyàn ń bọ.Ó tilẹ̀ wà nínú bíbélì àti kùránì bí Ọlọ́run ṣe ń kìlọ nípa ẹ̀sìn ìbọ̀rìṣà fún áwọn ọmọ ìsírẹ́ẹ́lì.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Days of the Week in English (and the Best Tips to Learn Them)". Lingoda. 2024-05-20. Retrieved 2024-07-19.