Ọkọ ẹrú Barbary

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìràpadà àwọn òùndè Krìtẹ́nì nípasẹ̀ Mercedarian ní àwọn Ìpínlẹ̀ Barbary
Etí odò Barbary

Oko ẹrú Barbary jẹ́ àwọn ọjà ẹrú tí ó wà ní àwọn Ìpínlẹ̀ Barbary. Àwọn jàndùkú odò tí ó jẹ́ ọmọ Barbary ya wọ àwọn ọkọ̀ ojú omi, ìlú ẹgbẹ́ odò láti ItalyNetherland, Ireland àti gúúsù apá ìwọ̀ oòrùn Britain, títí dé àríwá Iceland àti Ìlà-Oòrùn Mediterra.

Apá ìlà-oòrùn Mediterranean Ottoman ni ìṣẹ̀lẹ̀ yí wọ́sí jùlọ.[1] Títí di àwọn ọdún 1700s, ìwà jàndùkú jẹ́ ǹkan tí ó sì ń da Aegean láàmú.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Bradford, Ernle (1968). Sultan's Admiral. the Life of Barbarossa (First ed.). Harcourt Brace World. https://www.amazon.com/Sultans-Admiral-Barbarossa-Ernle-Bradford/dp/B00ARK1Z6G. 
  2. Ginio, Eyal (2001). "Piracy and Redemption in the Aegean Sea during the First Half of the Eighteenth Century." (in en). Turcica 33: 135–147. doi:10.2143/TURC.33.0.484. https://www.academia.edu/3084432. "consistent threat to maritime traffic in the Aegean"