Ọlábísí Afọlábí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọlábísí Afọlábí tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1975 (31 October 1975) jẹ́ gbajúmọ̀ eléré ìdárayá ẹlẹ́sẹ̀-ehoro [1] nígbà kan rí, tí ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ÌlọrinÌpínlẹ̀ Kwara. Ó gbajúmọ̀ nípa eré sísá oníwọ̀n irínwó mítà. Ó wà lára ìkọ̀ ẹgbẹ́ eléré tí wọ́n gba àmìn-ẹ̀yẹ bàbà ní ìdíje Òlíḿpíìkì lọ́dún 1996 nínú ìdíje eré gbagigbagi oníwọ̀n 4 x 400.[2]

Ó gbàmìn ẹ̀yẹ àwọn ọ̀jẹ̀ wẹ́wẹ́ àgbáyé nínú eré sísá lọ́dún 1994 àti àmìn idẹ fún eléré ilẹ̀ adúláwọ̀ lọ́dún 1995.

Ó ti bímọ báyìí lẹ́yìn tó lọ́kọ.

Àtẹ àṣàyàn àwọn àṣeyọrí ìdíje rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Representing Nàìjíríà Nàìjíríà
1993 Universiade Buffalo, United States 3rd 4 × 400 m relay 3:34.97
World Championships Stuttgart, Germany 10th (h) 4 × 400 m relay 3:33.12
1994 African Junior Championships Algiers, Algeria 1st 400 m 53.59
1st 4 × 100 m relay 46.15
2nd 4 × 400 m relay 3:45.41
World Junior Championships Lisbon, Portugal 1st 400 m 51.97
14th (h) 4 × 400 m relay 3:49.16
Commonwealth Games Victoria, Canada 7th 400 m 52.21
4 × 400 m relay DQ
1995 World Championships Gothenburg, Sweden 25th (h) 400 m 51.79
6th 4 × 400 m relay 3:27.85
Universiade Fukuoka, Japan 1st 400 m 50.50
All-Africa Games Harare, Zimbabwe 3rd 400 m 51.53
1996 Olympic Games Atlanta, United States 13th (sf) 400 m 51.40
2nd 4 × 400 m relay 3:21.04
1997 World Indoor Championships Paris, France 12th (sf) 400 m 53.33
World Championships Athens, Greece 13th (sf) 400 m 51.44
7th 4 × 400 m relay 3:30.04
1999 World Championships Seville, Spain 8th (sf) 400 m 50.40
All-Africa Games Johannesburg, South Africa 2nd 400 m 50.34
2000 Olympic Games Sydney, Australia 20th (qf) 400 m 51.87
4th 4 × 400 m relay 3:23.80
2002 Commonwealth Games Manchester, United Kingdom 3rd 4 × 400 m relay 3:29.16
2003 World Championships Paris, France 12th (sf) 400 m 51.38
All-Africa Games Abuja, Nigeria 8th 400 m 52.77
1st 4 × 400 m relay 3:27.76

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Olabisi AFOLABI - Profile". worldathletics.org. Retrieved 2020-11-06. 
  2. "Afolabi, Bisi". Encyclopedia.com. 2020-10-19. Retrieved 2020-11-06.