Jump to content

147 Protogeneia

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
147 Protogeneia
A three-dimensional model of 147 Protogeneia based on its light curve
Ìkọ́kọ́wárí[1] and designation
Kíkọ́kọ́wárí látọwọ́ Lipót Schulhof
Ọjọ́ ìkọ́kọ́wárí 10 July 1875
Ìfúnlọ́rúkọ
Sísọlọ́rúkọ fún Protogeneia
Minor planet
category
Main belt
Àsìkò 31 July 2016 (JD 2457600.5)
Aphelion3.2230 AU (482.15 Gm)
Perihelion 3.04727 AU (455.865 Gm)
Semi-major axis 3.13512 AU (469.007 Gm)
Eccentricity 0.028020
Àsìkò ìgbàyípo 5.55 yr (2027.6 d)
Average orbital speed 16.82 km/s
Mean anomaly 92.9051°
Inclination 1.9309°
Longitude of ascending node 248.357°
Argument of perihelion 100.692°
Iyeìdáméjì ìfẹ̀kiri 66.465±2.55 km
59.22 ± 5.225 km
Àkójọ (1.23 ± 0.05) × 1019 kg
Iyeìdáméjì ìṣùpọ̀ 14.13 ± 3.78 g/cm3>
Equatorial surface gravity0.0371 m/s²
Equatorial escape velocity0.0703 km/s
Rotation period 7.8528 h (0.32720 d)
Geometric albedo0.0492±0.004
Ìgbónásí ~157 K
Spectral typeC
Apparent magnitude 12.4 to 14.5
Absolute magnitude (H) 8.27
8.8

147 Protogeneia jẹ́ ìgbàjá tó fẹ̀ nínú àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré tí Lipót Schulhof tí ó jẹ́ onímọ̀ ìràwọ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè Hungary ṣàwárí rẹ̀ ní Ọjọ́ kẹwá Oṣù keje ọdún lati ìwòràwọ̀ tí ó ̣se lati Vienna; Èyí nìkan ni àwárí tí ó ṣe nínú àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré. Orúkọ rẹ̀ jẹ́ Gríkì tí ó túmọ̀ sí "Àkọ́bí", Karl L. Littrow ló mú orúkọ yìí nítorí èyí jẹ́ ìsọ̀gbé oòrùn kékeré àkọ́kọ́ tí onímọ̀ ìràwọ̀ tí wọ́n ti mọ̀ tẹ́lẹ̀ sí iṣẹ́ míràn nínú ẹ̀ka ìtòràwọ̀.

Àwọn ìtọ́kasi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]