Jump to content

Abba Kabir Yusuf

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

A bi Abba Kabir Yusuf ni ojo karun osu kinni odun (1963)[2] O je oloselu Naijiria to je gomina ipinle Kano ni odun 2023. O sise gege bi komisanna ti igbimo alase ni ipinle Kano lati odun 2011 si 2015.

Abba Kabir Yusuf