Jump to content

Abdullah Kejì ilẹ̀ Jọ́rdánì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Abdullah II)
Abdullah II
Pentagon on April 5, 2001
Reign 7 February 1999 – present
Enthronement 9 June 1999
Predecessor Hussein
Heir-apparent Crown Prince Hussein
Consort Rania Al-Yassin
Issue
Hussein, Crown Prince of Jordan
Princess Iman
Princess Salma
Prince Hashem
House Hashemite
Father Hussein of Jordan
Mother Princess Muna al-Hussein
Religion Sunni Muslim

Abdullah II bin al-Hussein OIH (Lárúbáwá: الملك عبد الله الثاني بن الحسين‎, al-Malik ʿAbdullāh aṯ-ṯānī bin al-Ḥusayn ibi ni Amman, 30 January 1962) ni Oba Hashemite Ileoba Jordani. O gun ori oye ni 7 February 1999 leyin iku baba re Oba Hussein. Oba Abdullah je omo ebi iran Hashemite.[1] Abdullah ti fe Rania niyawo lati 1993.



  1. Kingabdullah.jo (2006), His Majesty King Abdullah II: King of the Hashemite Kingdom of Jordan. Royal Hashemite Court. Retrieved on 14 December 2007