Abebech Afework

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
During Rotterdam Marathon in 2014

Abebech Afework Bekele ni a bini ọjọ kọkanla, óṣu December ni ọdun 1990 jẹ akọṣẹmọsẹ elere sisa ti ọna jinjin to dari lori idaji marathon[1]. Abebech ṣóju fun órilẹ ede Ethiopia ninu idije IAAF agbaye cross country ti iadaji marathon ati idije IAAF agbaye ti idaji marathon[2][3]. Awọn ere ti arabinrin naa ti yege julọ ni 1:10:30[4].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Abeche bere si ni dije ni ilẹ okun ni ọdun 2009 nibi to ti gbe ipo kẹta ni Maraton Idaji ti Udine ni 1:11:15. Ni ọdun naa, Arabinrin naa yege ninu Idaji Marathon ti Arezzo kekere. Ni óṣu January, ọdun 2011, Abebech yege ninu Idaji Marathon ti Egmond nibi to ti sare fun Club ti ere sisa defenc ilẹ Ethiopia[5]. Ni ọdun 2012, Abebech gbe ipo kẹfa ninu idije cross country ti ilẹ Afirica pẹlu ẹgbẹrun mẹwa metres ati iṣẹju ti 31:48.53 ni Prefontaine Classic. Ni óṣu july, 2012 arabinrin naa gbe ipo kẹta ni idaji Marathon ti Bogotà[6]. Ni ọdun 2013, Abebech ṣè dada ninu marathon ti Rottedam pẹlu wakati 2:23:59[7].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Ethiopians break through in 50th Honolulu Marathon
  2. Abebech AFEWORK Profile
  3. Ethiopian runners for IAAF
  4. Personal bests
  5. Egmond Half Marathon
  6. Bogotá Half Marathon
  7. Marathon Rotterdam