Jump to content

Abobaku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:DMCÀdàkọ:Merge partner

Abobaku
AdaríNiji Akanni
Olùgbékalẹ̀Femi Odugbemi
Òǹkọ̀wéDapo Olawale
Ìyàwòrán sinimáNiji Akanni
Ilé-iṣẹ́ fíìmùDVWORX Studio
Déètì àgbéjáde2010
Àkókò35 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèYoruba and subtitled in English

Abobaku jẹ fiimu kukuru ti won se ni 2010 nipasẹ Femi Odugbemi ati oludari ni Niji Akannii.[1] Fiimu naa gba ami eye fiimu to ta yo ni nu awon fiimu to kukuuru ju ni igba gede Zuma Film Festival ni odun 2010 ati ami eye fun eso ti o dara julọ ni ibi ayeye ’’Africa Movie Academy Awards’’ ele kefa iru e ti o waye ni ọjọ kewa osu Kẹrin ọdun 2010 ni Ile-iṣẹ Aṣa Gloryland ni agbegbe Yenagoa, ni Ipinle Bayelsa, orilede Niajiria..[2][3]

  1. "Abobaku! - The Nation". thenationonlineng.net. Retrieved 2015-04-12. 
  2. "AMAA 2010: 280 films entered, as Ghana hosts nomination party - Vanguard News". vanguardngr.com. Retrieved 2015-04-12. 
  3. Krings, M.; Okome, O. (2013). Global Nollywood: The Transnational Dimensions of an African Video Film Industry. Indiana University Press. p. 44. ISBN 9780253009425. https://books.google.com/books?id=uTVlKirJmGgC. Retrieved 2015-04-12.