Àṣínììsì
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Achinese)
Èdè àwọn Malayic (Maláyíìkì) kan ni eléyìí tí ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ fún àwọn èdè tí wọ́n ń pè ní Austronesian (èdè tí wọ́n ń sọ ní ilẹ̀ Australia, New Zealand àti Asia). Àwọn ènìyàn bú mílíonù mẹ́ta ni ó ń sọ èdè Àsíníìsì ní apá kan ilẹ̀ Sumatra àti Indonesia. Wọ́n tún máa ń pe èdè yìí ní Achehnese àti Atjehnese. Àkọtọ́ Rómáànù ni wọ́n fi ko èdè yìí sílẹ̀.