Jump to content

Achu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oúnjẹ Achu

Achu jẹ́ oúnjẹ ilẹ̀ adúláwọ̀ tó gbajúmọ̀ láàrin àwọn ara ́orílẹ̀-èdè kamẹrúùnù. Ó jẹ́ oúnjẹ kan tí wọ́n maá n fi iyán kókò pèlòo rẹ̀ pẹ̀lú epo pupa pẹ̀lú pànmá àti àwọn èròjà mìíràn.