Jump to content

Achu soup

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Achûë soup
Achu soup or Yellow soup
Alternative namesYellow soup
Place of originCameroon
Region or stateNorth-West
 

Achu soup jẹ́ oúnjẹ ìbílẹ̀ tàbí kí a sọ pé ọbẹ̀ ní Cameroon.[1] Iṣu ewùrà ni wọ́n fi ṣe oúnjẹ yìí.[2] Oríṣi èròjà ìsebẹ̀, epo, omí àti "canwa or Nikki" (limestone), àti ẹja ni àwọn èròjà tí wọ́n fi ń sè é.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]