Ade Hassan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ade Hassan Adétọ́lá Kúnlé-Hassan, tí a mọ̀ sí Ade Hassan, MBE, (ọjọ́ ìbí April 1984) Ó jẹ́ onísòwò Obìnrin láti ìlú òyìnbó tí ó dá Nubian Skin sílẹ́ ni 2004.

ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Hassan ní oṣù igbe ní ọdún 1984. A tọ́ ọ díẹ́ ní Nàìjíríà, ó sì ń sọ Yorùbá. Àwọn òbí rẹ̀ méjèèjì jẹ́ onísòwò. Ó lọ ilé ìwé gíga ní Duke University ní ilẹ̀ ọba níbití ó tí kọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Ékọ́nọ́míísì. Lẹ́yìn tí ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè dìgírì ní ilé ìwé Oriental and African Studies ní ìlú òyìnbó.

Ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ wáyé ní private-equitybusiness. Ṣùgbọ́n ó àkókò díẹ̀ níbẹ̀ láti lọ fún ẹ̀kọ́ gígé àti rírán fún ọdún kan. Ó da Nubian Skin sílẹ̀, tí ó ń sé àwọ̀tẹ́lẹ̀ ní dúdú tones fún àwọn obìnrin, 2014 lẹ́yìn tí ó tí lè ra aṣọ fún ara rẹ̀ ní oríṣiríṣi àwọ̀. Ní 2014, a sọ ọ́ di Onísòwò oge ti ọdún náàr ní the Great British Entrepreneur Awards. Ní oṣù ọ̀wàrà ọdún 2015, A yan Ade's brand, Nubian Skin, fún Hosiery Brand ti ọdún náà ní UK Lingerie Awards[10] Ó sì jáwé Olúborí UK's Favourite British Designer ti ọdún náà. A yàn-án gẹ́gẹ́bí ọmọ ẹgbẹ́ ti Order of the British Empire ní 2017 Queen's Birthday Honours for services to fashion.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]