Admiralty Circle Plaza
Ìrísí
Admiralty Circle plaza wa ni ijoba ibile Eti-Osa ni Ipinle Eko ni Nàìjíríà . A dasilẹ lati gba owó ní ònà Lekki-Eti-Osa expressway, ònà tí o to kilometer kandinlogota(49km) Kíko plaza náà jẹ adehun laarin ijọba ipinlẹ Eko ati Messrs ikeja Concession Company Limited LCC.[1] Iṣẹ bẹrẹ ni plaza ni ọjọ 5 Oṣu Kini(5 January), ọdun 2011.[2]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Eribake, Akintayo (December 15, 2011). "Tension as Lagos govt insists on toll collection". Vanguard News. Retrieved September 12, 2022.
- ↑ "Admiralty Circle Plaza Archives - P.M. News". PM News Nigeria. September 12, 2022. Retrieved September 12, 2022.