Adowa smart
Ìrísí
Adowa smart | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Belinda Naa Ode Oku 5 Oṣù Kẹ̀wá 1970 Accra |
Orílẹ̀-èdè | Ghanaian |
Orúkọ míràn | Adwoa Smart |
Iṣẹ́ | Actress |
Gbajúmọ̀ fún | Obra, Efie Wura, Yaa Asantewa, Money bag , Father and Son |
Parents |
|
Belinda Naa Ode Oku (tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kàrún oṣù kẹwàá ọdún 1970) jẹ́ òṣẹ̀rébìnrin ilẹ̀ Ghana tí ọ̀pọl ènìyàn mọ̀ sí "Adwoa Smart". Wọ́n bí i sí ìlú Abossey Okai, ní ìgbèríko Accra ní ìlú Ghana. Adwoa tí kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù, bẹ́è sì ni ó ti kópa nínú fọ́nrán orin lóríṣiríṣi. Adwoa bọ́ sí gbàgede lẹ́yìn tí ó kópa nínú fíìmù "Obra" (Life) èyí tí wọ́n ṣàfihàn ní orí GTV.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Belinda Naa Ode Oku, Adwoa Smart". www.ghanaweb.com. Retrieved 2019-06-29.