Jump to content

Afang soup

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Afang (ọbẹ̀))

Obe afangi (ti a ko gbodo sipe ni obe okazi tabi obe ukazi, obe ti awọn ti o wa ní ìyá gúúsù-iwo oorun ile Naijiria), je obe ti o ṣẹda lati ọdọ awọn Efiki ni Ìpínlẹ̀ Cross River ati awọn Ibibio ni Ìpínlẹ̀ Akwa Íbọm ni ìyá gúúsù ilẹ Nàìjíríà.[1] O jẹ oúnjẹ ti oni okiki gidigan ni ile Nàìjíríà àti àwọn apá kankan ni Afrika. Òsé pataki paapa ni ọdọ àwọn Ibibio ati awọn ara Anangi ti Ìpínlẹ̀ Akwa Íbọm ati Ìpínlẹ̀ Cross River ti wọn ti gba ounjẹ yii gẹgẹ bíi lara àṣà àti ìṣe wọn.[2] A man jẹ oúnjẹ yii nile, ati ni oriṣiriṣi ayẹyẹ bíi igbeyawo, ìtoku, ati ajọdun paapa ni ìyá guusu- iwọ oorun ile Naijiria. Ọbẹ afangi je obe ti ọ ni aanfani lọpọlọpọ lara atipe owo ti a yóó na lati ṣe lè ba apo onikaluku mu. Awọn eroja ti a ma fi se ọbẹ afangi ni eran, ẹja,epo pupa, èdè, ata,shaki, ẹfọ gbure, ewe gbure, alubosa, iyọ, ati bebe lọ.

Ọbẹ̀ Afang
  1. Ukpong, Cletus (2016-04-19). "Nollywood Actress, Omoni Oboli, falls in love with Afang soup". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-02-22.