Agbádá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
A Grand boubou.

Agbada (ni Yoruba, Dagomba), Babban Riga (ni Hausa), K'sa (ni Tuareg) ati Grand Boubou je oruko aso towopo ti awon eniyan n wo kakiri ile Iwoorun Afrika.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]