Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gwagwalada

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gwagwalada wa ni je ara àwon agbegbe ibile ìjoba tí o wà ní ilu Abuja, olú-ìlú Naijiria. Ìjoba ibile Gwagwalada ní ilé 1036km square àti olùgbé 158,618(gegebi ètò ìkà ènìyàn ti 2006) [1]



  1. "Gwagwalada (Local Government Area, Nigeria)". Population Statistics, Charts, Map and Location. 2016-03-21. Retrieved 2022-03-18.