Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gamawa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Gamawa)
Gamawa
LGA and town
Àwòrán aàfin Emir ti ìlú Gamawa
Àwòrán aàfin Emir ti ìlú Gamawa
Gamawa is located in Nigeria
Gamawa
Gamawa
Location in Nigeria
Coordinates: 12°08′N 10°32′E / 12.133°N 10.533°E / 12.133; 10.533Coordinates: 12°08′N 10°32′E / 12.133°N 10.533°E / 12.133; 10.533
Country Nigeria
StateBauchi State
Area
 • Total2,925 km2 (1,129 sq mi)
Population
 (2006 census)
 • Total286,388
Time zoneUTC+1 (WAT)
3-digit postal code prefix
752
ISO 3166 codeNG.BA.GM

Gamawa jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ kan ní orílẹ̀-èdè Naijiria, ní ipinle Bauchi, tó já mọ́ Ipinle Yobe, èyí tó wà ní apá ìlà-oòrùn ti Naijiria. Olú ìlú náà wà ní ìlú Gamawa.

Ó ní ìwọ̀n ìtóbi tó 2,925 km2 àti èrò tó ń lọ bíi 286,388, ìyẹn ní ọdún 2006.

Àwọn èyà tó wà ní ìlú náà ni: àwọn Hausa, Fulani, Fulfulde àti Kare.[1]

Kóòdù ìfìwéráńṣé agbègbè naà 752.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "State maps". Nigerian National Bureau of Statistics. Archived from the original on 2010-05-01. Retrieved 2010-05-19.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 2012-11-26. Retrieved 2009-10-20.