Jump to content

Agbezin Bamidele George

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

A bí ògbẹ́ni Agbezin Bamidele George ní ojọ kẹtàdínlọgbọn oṣù keje ọdún 1973 ní erékùṣù èkó ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀ẹ̀de Nàíjíríà sínú ìdílé olóyè Agbezin latí ilu Togo tó sì fẹ́ ọmọ ìlu Nàíjíríà níyàwó.Olóyè Agbezin fúnrarẹ̀ jẹ́ agbẹ́gílére .Bamidele George fúnrarẹ̀ yan isẹ̀ fífí ọ̀dàdárà. .Bamidele lọ sí ile ẹ̀kọ́ alakọ́bẹ̀rẹ̀ ní ìlu Eko. Bakana ó tẹ̀síwáju Lati kẹ́kọ fine & Applied Art ni ilé ẹ̀kọ́ giga Institute of management & Technology tí ìpínlẹ̀ Enugu ó sì gboyè Higher National Diploma ninu isẹ́ Fífi Ọ̀da dárà. Gbàrà tó gboyèjáde ní ilé ẹ̀kọ́,nṣe lo gbájumọ́ isẹ́ ọwọ́ tó yànláàyò nínú ilé àdáni

níbi tó ngbé.