Agbon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Agbon

Igi agbon ( Cocos nucifera ) jẹ eya igi ọpẹ ( Arecaceae ) ati eya Cocos kan soso ti o ku. Ohun ti a n pe ni " agbon " [1] le tọka si gbogbo igi agbon, koro eso,tabi eso. Oruko yii wa lati oruko "Coco' eyi ti o je oruko Aguda atijo ti o tumo si ori, tabi agbari.

Awọn itọkasi.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Pearsall, J., ed (1999). "Coconut". Concise Oxford Dictionary (10th ed.). Oxford: Clarendon Press. ISBN 0-19-860287-1.