Àgèrè
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Agere (Drum))
ÀGẸ̀RẸ̀:-
A nlù agẹrẹ lọjọ ọdun awọn ọdẹ. Idi niyi ti a fi n pe Agẹrẹ ni ìlù ogun. Bi ọlọ́ọ́dẹ tàbí olórí ọdẹ kan bá ku ni a n lù agẹrẹ. Ọ̀wọ́ ìlù mẹta la papọ̀ se àgẹ̀rẹ̀ ògún.
(a) Àgẹ̀rẹ̀:- Eyí ni ìlù to tobi ju pátápátá. Igi la fi ngbẹ agẹrẹ. Oju meji Ọgbọọgba lo sì nì. Ìlù yi dabi ìbẹ̀mbẹ́. Awọ la fin bòó lójú ọ̀nà méjèèjì, okun la si nfi wa awọ ojú rẹ lọ́nà méjèèjì ki o le dún.
(b) Fééré:- Ìlù yii kere jù agẹrẹ lọ. Igi naa la fi gbẹ ẹ, ṣùgbọ́n ko fẹ to agẹrẹ.
(d) Aféré: Ìlù yii lo kere jù awọn meji ìsáájú lọ.