Jump to content

Ahriche

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ahriche ni oúnjẹ kan tó gbajúmọ̀ lórílẹ̀-èdè Mòrókò, ó sì wọ́pọ̀ láàrin àwọn ìran Zayanes àti Khénifra. Orúkọ oúnjẹ náà jẹyọ láti ibi pípèlò rè látàrí wípé ó pẹ̀lú fífi ìfun ẹran kọ́ sára igi, léyìí tí wón ò tẹ̀ẹ́ sórí àrò.