Jump to content

Akpororo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nigerian_Role_Model_Awards_3

Bowoto Jephthah Oluwatiseyifumi Tanimola ti inagijẹ rẹ njẹ Akpororo jẹ alawada ati óṣèrè lọkunrin ilẹ naigiria[1].

Igbèsi Àyè Àràkunrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Akpororo ni a bi tosi dagba si warri ni ipinlẹ Delta ṣugbọn to wa lati ilajẹ, ipinlẹ Ondo. Irin ajo arakunrin naa bẹrẹ gẹgẹbi ólórin ni ọdun 2008 nibi to ti pegede ninu idije zone ti calabar[2].

Ni 2009, Akpororo lọsi eko tosi kopa ninu idije nibi toti ṣè ipó keji. Ni óṣu August, ọdun 2014 arakunrin naa bẹrẹ awada rẹ akọkọ Akpororo vs Akpororo ni Hall ti shell ni MUSON Centre[3].

Ni ọdun 2014, Akpororo bẹrẹ irin ajó gẹgẹbi óṣèrè lọkunrin ninu filmu Headgone ati Antique[4][5]

Akpororo fẹ Josephine Ijeoma Abraham ni Surulere, Ipinlẹ eko ni ọjọ kẹrinla óṣu November, ọdun 2015[6][7].

Akpororo kẹẹkọ ni ilè iwè giga ti ipinlẹ ekó lori imọ sociology[8].

  1. http://encomium.ng/i-am-waiting-for-a-woman-who-will-pay-my-groom-price-akpororo/
  2. https://web.archive.org/web/20160817182049/http://nationalweekender.net/i-test-my-jokes-in-clubs-akpororo/
  3. https://dailypost.ng/2015/11/04/i-cried-when-they-paid-me-money-that-changed-my-life-akpororo/
  4. https://web.archive.org/web/20160817054108/http://dailymail.com.ng/new-nollywood-movie-the-antique-starring-olu-jacobs-bimbo-akintola-premieres-oct-19th/
  5. https://www.bellanaija.com/2014/11/hilarious-sound-sultan-ali-baba-basketmouth-2face-idibia-more-stars-feature-in-head-gone-watch-trailer/
  6. https://dnbstories.com/2022/01/full-details-of-akpororos-marriage-wife-and-children.html
  7. https://buzznigeria.com/intimate-details-of-akpororo-marriage-to-wife-josephine-ijeoma/
  8. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-11-23. Retrieved 2022-11-23.