Aláàfin Gberu
Ìrísí
Gberu fìgbà kan jẹ́ Aláàfin ti ìlú Ọ̀yọ́. Ó wà lórí oyè láti ọdún 1730 wọ ọdún 1746.[1]Gberu ni ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jambu, tó fi jẹ Baṣọ̀run (èyí tí ń ṣe olórí àwọn Ọ̀yọ́ Mèsì, àti olùdámọ̀ràn ìlú), àmọ́ wọ́n kẹ̀yìn si, nígbà tí àwọn méjèèejì bẹ̀rẹ̀ sí ní dìtẹ̀ mọ́ ara wọn.[2]
Lẹ́yìn tí wọ́n kọ̀ ọ́ bí ọba, Gberu pa ara rẹ̀.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Alaafin of Oyo: Wo Alàáfin 43 tó jẹ́ láti ìgbà ìwásẹ̀ ṣáajú Lamide Adeyemi tó ṣẹ̀ṣẹ̀ wàjà". BBC News Yorùbá. 2022-04-24. Retrieved 2024-06-17.
- ↑ Johnson, Samuel (August 2011). The history of the Yorubas : from the earliest times to the beginning of the British Protectorate. ISBN 0948390891. OCLC 989713421.
- ↑ Law, R. C. C. (1971). "The constitutional troubles of Ọyọ in the eighteenth century". The Journal of African History 12 (1): 25–44. doi:10.1017/s0021853700000050. ISSN 0021-8537.