Jump to content

Aláàfin Kòrì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Aláàfin Kòrì jẹ́ Ọba Àlááfín Ọ̀yọ́ láàárín ọdún 1340. Lásìkò rẹ̀ ni ó wọ́n dá ìlú Ẹdẹ àti Òṣogbo sí lẹ̀.[1] Ìtàn sọ wípé, òun ló rán Tìmì lọ sí Ẹdẹ láti bá àwọn Ìjẹ̀ṣà jà. Lẹ́yìn ìjà náà ni Tìmì fi ara rẹ̀ jọba l'Ẹ́dẹ. Èyí ló fàá tí wọ́n fi ń pe òye ọba ìlú Ẹdẹ ni Tìmì. Odidi ọdún àádọ́ta ni Àlááfín Kòrì lò lórí ìtẹ́ Ọba Àlááfín. Èyí ni wọ́n fi ń sọ pé òun ni ìgbà rẹ̀ gùn jú nínú àwọn ọba Àlááfín Ọ̀yọ́

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]