Jump to content

Aláàfin Lábísí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Aláàfin Lábísí ni Aláàfin Ọ̀yọ́ tí wọ́n fi j'ọ̀ba lọ́dún 1750 ṣùgbọ́n tí kò d'ádé nítorí pé ó kú ní nǹkan bí ọjọ́ mẹ́ẹ̀dógún[1][2] sí mẹ́tàdínlógún[3] kí wọ́n tó dé e l'ádé. Òun ni Aláàfin Ọ̀yọ́ tí ọjọ́ tí ó lò lórí ìtẹ́ kéré jùlọ. Rògbòdìyàn àti ìjà tí Baṣọ̀run Gáà gbé kò ó nígbà tí ó j'ọba ló mú un pa ara rẹ̀.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Alaafin of Oyo: Wo Alàáfin 43 tó jẹ́ láti ìgbà ìwásẹ̀ ṣáajú Lamide Adeyemi tó ṣẹ̀ṣẹ̀ wàjà". BBC News Yorùbá. 2022-04-24. Retrieved 2024-06-25. 
  2. Okùnadé, Johnson (2020-03-11). "The History of Old Oyo Empire (Oyo Ile) and Past Alaafin". Johnson Okunade Afro-Cultural Hub. Retrieved 2024-06-25. 
  3. "IS OYO HISTORY REPEATING ITSELF?". Google Accounts. 2007-10-22. Retrieved 2024-06-25.