Jump to content

Aláàfin Olúàṣo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Aláàfin Olúàṣo jẹ́ ọba Ọ̀yọ́ tí ó gbajúgbajà fún ẹwà àti fìrìgbọ̀n rẹ̀. Àwọn àkọni ìgbà náà ṣàlàyè pé àsìkò tó jẹ Ọba Ọ̀yọ́, àlàáfíà, ẹ̀mí-gígùn àti ìfẹ́ jọba ní ìlú. Ó kọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àfin sí inú ìlú, ó sì fẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìyàwó, tí wọ́n sì bí ọmọ rẹpẹtẹ fún un.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Alaafin Oluaso: Wo Aláàfin tó bí ọmọ 1,460, ayaba mẹ́sàn-án bí ìbejì lọ́jọ́ kan ṣoṣo ní ìgbà mẹ́ta". BBC News Yorùbá. 2023-02-05. Retrieved 2024-06-20. 
  • Samuel Johnson, Obadiah Johnson. The History of the Yorubas, From the Earliest of Times to the Beginning of the British Protectorate. p 158