Alemitu Bekele Degfa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Alemitu Bekele
Celebrating gold in Turin
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèTurkish
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kẹ̀sán 1977 (1977-09-17) (ọmọ ọdún 46)
Shoa, Ethiopia
Ibùgbéİstanbul, Turkey
Sport
Erẹ́ìdárayáRunning
Event(s)3000 metres, 5000 metres
ClubÜsküdar Belediyespor
Achievements and titles
Personal best(s)3000m: 8:35.19 5000m: 14:42.62

Alemitu Bekele Degfa ni a bini ọjọ kejila, óṣu september, ọdun 1977 jẹ elere sisa lobinrin ti órilẹ Ethiopia to da lori metres ti ẹgbẹrun marun[1].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bekele pari pẹlu ipo keje ninu ere olympic ti ọdun 2008. Ni ọdun 2009, Arabinrin naa gba ami ẹyẹ ọla ti wura ninu idije ti inu ile ti ilẹ Ethiopia[2]. Ni ọdun 2010, Degfa kopa ninu idije ere sisa ti ilẹ Ethiopia ti ẹgbẹrun marun metres pẹlu iṣẹju 52.20 ati iṣẹju aya kẹrin lèèlogun. Ni ọdun 2010, Degfa kopa ninu Cup Continental ti IAAF to si gba ami ẹyẹ ọla ti silver[3]. Ni ọdun 2011, Degfa gba órukọ fun Üsküdar Belediyespor ni Cinque Mulini[4].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Alemitu Bekele
  2. Footer European Indoor Champions 3000m Women
  3. IAAF
  4. Lamdassem and Bekele are triumphant in the Cinque Mulini