Jump to content

Ali Hassan Mwinyi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ali Hassan Mwinyi
2nd President of Tanzania
In office
November 5, 1985 – November 23, 1995
AsíwájúJulius Nyerere
Arọ́pòBenjamin Mkapa
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kàrún 1925 (1925-05-08) (ọmọ ọdún 99)
Zanzibar
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCCM
(Àwọn) olólùfẹ́Siti Mwinyi

Ali Hassan Mwinyi (ojoibi May 8, 1925, Kivure, ni Coast Region, Tanzania - 29 Oṣù Kejì 2024) je oloselu ara orile-ede Tanzania. O je Aare ekeji ile Tanzania lati 1985 de 1995.