Jump to content

Alo apamo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Alo apamo ni irufe alo ti o ni ibere ati idahun oju ese ninu.[1]

  • Yara kotopo kan kiki egun ........ idahun Enu
  • Ile afinju kiki egbin.............idahun Ibepe
  • Awe obi kan a je de oyo.......idahun Ahon
  • Oruku bi igba omo, gbogbo won lo le tiroo.......Idahun ewa
  • Okun n ho ge, Osa n ho gee, Omo buruku kori bo o.......idahun Orogun. [2]

Alo je ere ti wopo laarin awon omode, ere osupa si ni pelu, awon omode maa n kora jo lale lati se ere yii lati dekun ere asekudorogbo, won a kora won lo sile agba to gbo aloo yanranyan lati gbo alo loore-koore lojo ro. eyi ko tumo si pe omode ko le saaju alo pipa, ni won se n powe pe "omode ti yoo je asamu ati kekere ni yoo ti maa senu samu-samu" eyi n safihan igboya han lara irufe omo ti o ba n saaju alo pipa laarin awon akegbe re yooku.

Awon itokasi

  1. "Awon alo apamo Yoruba (Yomba conundrums)". WorldCat.org. Retrieved 2024-01-27. 
  2. Dreams, Waking; Was, He. "Folk tales from many lands.". Digital.library server at Penn Libraries. Retrieved 2024-01-27.