Alonge

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Alonge je Oruko pataki ni ile yoruba, Awon to on je oruko yi, wa ni oniruiru Ipinle ni orile ede naijiria. Awon kan wa ni ipinle Ondo, Osun, Oyo ati bee bee lo. Itumo oruko yii si ni "Eni to kere, sugbon ti o je akikanju". Ada pe re a si maa je "Longe" - Idi niyi ti owe yoruba kan se so wipe "Ewu nbe loko Longe, Longe funrara re ewu ni".