Amóráìtì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Amorite

Èdè Sèmítíìkì (Semitic) kan ni Amóráìtì (Amorite) tí wón ń so ní agbègbè àríwá Síríà (Syria) òde òní ní nnkan bí egbèrún méjì odún sí egbèrún kan àbò sáájú ìbí Kírísítì. Díè ni a mò nípa èdè yìí nítorí pé láti inú orúko ènìyàn àti àwon àkósílè díè tí a rí tí wón opé sí ara òkúta nìkan ni a mò nípa èdè yìí