Jump to content

Amúlétutù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Amúlétutù tàbí èro amúlétutù tí òpòlopò ènìyàn mò sí "AC" jé èro tí a fi ún mu ilé tùtù, amúlétutù má ún lo kemikali tí a mò sí "refrigerant" láti fa ooru kúrò ni inú ilé, apakan amúlétutù tí a mo sí "condenser" a sì ti oru na jade [1] Engr. Willis Havilland ní o kókó se èro amúlétutù ní odun 1902 [2] láti igba na, òpòlopò ilé ni o ti ún lo amúlétutù.

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "How Does Central Air Work". Carrier. 1902-07-17. Retrieved 2022-03-01. 
  2. "History Of Air Conditioner". Air Conditioning Systems Tips and Guide. Retrieved 2022-03-02.