Amane Beriso

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Amane Beriso
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́Amane Beriso Shankule
Ọmọorílẹ̀-èdèEthiopian
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹ̀wá 1991 (1991-10-13) (ọmọ ọdún 32)
Sport
Orílẹ̀-èdèEthiopia
Erẹ́ìdárayáSport of athletics
Event(s)Long-distance running
Coached byGemedu Dedefo
Achievements and titles
Personal best(s)
  • Marathon: 2:14:58 (Valencia 2022)

Amane Beriso Shankule ni a bini ọjọ kẹtala, óṣu October, Ọdun 1991 jẹ̀ elere sisa lobinrin ilẹ Ethiopia. Ni ọdun 2022, Arabinrin naa kopa ninu Marathon ti Valencia ni bi to ti gbe ipo kẹta[1].

Aṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Amane Beriso yege ninu Idaji Marathon ti Copenhagen ni Ọdun 2014. Ni ọdun 2015, Amane yege ninu Idaji Marathon ti Roma-Ostia pẹlu wakati 1:08:43. Ni ọdun 2016, Arabinrin naa kopa ninu Marathon ti ilẹ Dubai pẹlu wakati 2:20:48 nibi to ti gbe ipo keji. Ni ọdun 2017, Amane yege ninu Marathon ti Prague pẹlu wakati 2:22:15. Ni ọdun 2020, Amane yege ninu Marathon ti Mumbai pẹlu wakati 2:24:51[2]. Ni óṣu August, ọdun 2022, Amane yege ninu Marathon ti Mecico City pẹlu wakati 2:25:05[2]. Ni ọjọ kẹrin, óṣu December, ọdun 2022, Arabinrin naa yege ninu Marathon ti Valencia pẹlu wakati 2:14:58[3][4].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Amane Beriso Profile
  2. 2.0 2.1 Mumbai Marathon
  3. Beriso break course records in Valencia
  4. Valencia Marathon